Romans 15:23

Paulu ṣètò láti ṣé àbẹ̀wò sí Romu

23 aṢùgbọ́n báyìí tí kò tún sí ibòmíràn fún mi mọ́ láti ṣiṣẹ́ ní ẹkùn yìí, tí èmi sì ti ń pòǹgbẹ láti ọdún púpọ̀ sẹ́yìn láti bẹ́ yín wò,
Copyright information for YorBMYO